You are viewing a single comment's thread from:
RE: OGA OLE | ODUNLADE ADEKOLA AWARD WINNING YORUBA MOVIE
AWARDWINNINGYORUBAMOVIES je ikan lara awon channeli gbakongbi lori YouTube.afe ki e darapo mo wa ki a le ba ma fi awon ere ori itage da yin laraya. Idi pataki ti afi gbe YorubaHOOD+ si ori channeli ni wi pe, ari wi pe opolopo awon tiwatiwa ti gbagbe ede abinibi won ati fun awon ti won feran la ti ko ede YORUBA.